Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ogún ọdun ni Ahasi nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ọdun mẹrindilogun ni Jerusalemu, kò si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa Ọlọrun rẹ̀, gẹgẹ bi Dafidi baba rẹ̀.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:1-8