Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o rìn li ọ̀na awọn ọba Israeli, nitõtọ, o si mu ki ọmọ rẹ̀ ki o kọja lãrin iná pẹlu, gẹgẹ bi iṣe irira awọn keferi, ti Oluwa le jade niwaju awọn ọmọ Israeli.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:1-7