Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si sun ẹbọ ọrẹ-sisun rẹ̀ ati ọrẹ-jijẹ rẹ̀, o si ta ohun-mimu rẹ̀ silẹ, o si wọ́n ẹ̀jẹ ọrẹ-alafia rẹ̀ si ara pẹpẹ na.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:5-16