Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọba si ti Damasku de, ọba si ri pẹpẹ na: ọba si sunmọ pẹpẹ na, o si rubọ lori rẹ̀.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:3-17