Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o mu pẹpẹ idẹ ti o wà niwaju Oluwa kuro lati iwaju ile na, lati agbedemeji pẹpẹ na, ati ile Oluwa, o si fi i si apa ariwa pẹpẹ na.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:9-20