Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 16:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Urijah alufa si ṣe pẹpẹ kan gẹgẹ bi gbogbo eyiti Ahasi ọba fi ranṣẹ si i lati Damasku wá; bẹ̃ni Urijah alufa ṣe e de atibọ̀ Ahasi ọba lati Damasku wá.

2. A. Ọba 16

2. A. Ọba 16:5-14