Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jeroboamu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, ani, pẹlu awọn ọba Israeli; Sakariah ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:28-29