Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 14:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù iṣe Jeroboamu ati gbogbo eyiti o ṣe, ati agbara rẹ̀, bi o ti jagun si, ati bi o ti gbà Damasku, ati Hamati, ti iṣe ti Juda, pada fun Israeli, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli?

2. A. Ọba 14

2. A. Ọba 14:25-29