Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni kò kù ninu awọn enia fun Jehoahasi, bikòṣe ãdọta ẹlẹṣin, ati kẹkẹ́ mẹwa, ati ẹgbãrin ẹlẹsẹ̀; nitoriti ọba Siria ti pa wọn run, o si ti lọ̀ wọn mọlẹ bi ẽkuru.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:1-14