Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iyokù iṣe Jehoahasi, ati gbogbo eyiti o ṣe, ati agbara rẹ̀, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:5-13