Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Ṣi fèrese ilà õrùn. On si ṣi i. Nigbana ni Eliṣa wipe, Ta. On si ta. O si wipe, Ọfà igbala Oluwa, ati ọfà igbala lọwọ Siria: nitori iwọ o kọlù awọn ara Siria ni Afeki, titi iwọ o fi run wọn.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:8-18