Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun ọba Israeli pe, Fi ọwọ rẹ le ọrun na: on si fi ọwọ rẹ̀ le e: Eliṣa si fi ọwọ tirẹ̀ le ọwọ ọba.

2. A. Ọba 13

2. A. Ọba 13:15-22