Yorùbá Bibeli

2. A. Ọba 10:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun Jehu pe, Nitoriti iwọ ti ṣe rere ni ṣiṣe eyi ti o tọ́ li oju mi, ti o si ti ṣe si ile Ahabu gẹgẹ bi gbogbo eyiti o wà li ọkàn mi, awọn ọmọ rẹ iran kẹrin yio joko lori itẹ Israeli.

2. A. Ọba 10

2. A. Ọba 10:21-32