Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn alufa si gbe apoti-ẹri majẹmu Oluwa wá si ipò rẹ̀ sinu ibi-idahùn ile na, ni ibi mimọ́-julọ labẹ iyẹ awọn kerubu.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:1-8