Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn kerubu nà iyẹ wọn mejeji si ibi apoti-ẹri, awọn kerubu na si bò apọti-ẹri ati awọn ọpá rẹ̀ lati oke wá.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:1-9