Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bẹ̃ li a pa a laṣẹ fun mi nipa ọ̀rọ Oluwa wipe, Máṣe jẹ onjẹ, má si ṣe mu omi, bẹ̃ni ki o má si ṣe pada li ọ̀na kanna ti o ba wá.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:2-18