Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Enia Ọlọrun na si wi fun ọba pe, Bi iwọ o ba fun mi ni idaji ile rẹ, emi kì yio ba ọ lọ ile, emi kì yio si jẹ onjẹ, bẹ̃ni emi kì yio si mu omi nihin yi.

1. A. Ọba 13

1. A. Ọba 13:4-15