Yorùbá Bibeli

Rut 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Mú aṣọ-ileke ti mbẹ lara rẹ wá, ki o si dì i mú: nigbati o si dì i mú, o wọ̀n òṣuwọn ọkà-barle mẹfa, o si gbé e rù u: on si wọ̀ ilu lọ.

Rut 3

Rut 3:14-18