Yorùbá Bibeli

Rut 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si dubulẹ lẹba ẹsẹ̀ rẹ̀ titi di owurọ̀: o si dide ki ẹnikan ki o to mọ̀ ẹnikeji. On si wipe, Má ṣe jẹ ki a mọ̀ pe obinrin kan wá si ilẹ-ipakà.

Rut 3

Rut 3:7-18