Yorùbá Bibeli

Rom 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ileri fun Abrahamu tabi fun irú-ọmọ rẹ̀ pe, on ó ṣe arole aiye, kì iṣe nipa ofin, bikoṣe nipa ododo igbagbọ́.

Rom 4

Rom 4:6-17