Yorùbá Bibeli

Rom 4:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati baba ikọla fun awọn ti kò si ninu kìki awọn akọla nikan, ṣugbọn ti nrin pẹlu nipasẹ igbagbọ́ Abrahamu baba wa, ti o ni li aikọla.

Rom 4

Rom 4:6-17