Yorùbá Bibeli

Rom 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa si mọ̀ pe ohunkohun ti ofin ba wi, o nwi fun awọn ti o wà labẹ ofin: ki gbogbo ẹnu ki o le pamọ́, ati ki a le mu gbogbo araiye wá sabẹ idajọ Ọlọrun.

Rom 3

Rom 3:10-24