Yorùbá Bibeli

Rom 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun kò ta awọn enia rẹ̀ nù ti o ti mọ̀ tẹlẹ. Tabi ẹnyin kò mọ̀ bi iwe-mimọ́ ti wi niti Elijah? bi o ti mbẹ̀bẹ lọdọ Ọlọrun si Israeli, wipe,

Rom 11

Rom 11:1-7