Yorùbá Bibeli

Rom 11:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NJẸ mo ni, Ọlọrun ha ta awọn enia rẹ̀ nù bi? Ki a má ri. Nitori Israeli li emi pẹlu, lati inu irú-ọmọ Abrahamu, li ẹ̀ya Benjamini.

Rom 11

Rom 11:1-6