Yorùbá Bibeli

O. Daf 133:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O dabi ororo ikunra iyebiye li ori, ti o ṣàn de irungbọn, ani irungbọn Aaroni: ti o si ṣàn si eti aṣọ rẹ̀;

O. Daf 133

O. Daf 133:1-3