Yorùbá Bibeli

Neh 4:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, lati ọjọ na wá, idaji awọn ọmọkunrin mi ṣe iṣẹ na, idaji keji di ọ̀kọ, apata, ati ọrun, ati ihamọra mu; awọn olori si duro lẹhin gbogbo ile Juda.

Neh 4

Neh 4:13-23