Yorùbá Bibeli

Neh 4:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati awọn ọta wa gbọ́ pe, o di mimọ̀ fun wa, Ọlọrun ti sọ ìmọ wọn di asan, gbogbo wa si padà si odi na, olukuluku si iṣẹ rẹ̀.

Neh 4

Neh 4:9-22