Yorùbá Bibeli

Mat 20:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn kì yio ri bẹ̃ lãrin nyin: ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba fẹ pọ̀ ninu nyin, ẹ jẹ ki o ṣe iranṣẹ nyin;

Mat 20

Mat 20:20-33