Yorùbá Bibeli

Mat 20:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Jesu pè wọn sọdọ rẹ̀, o si wipe, Ẹnyin mọ̀ pe awọn ọba Keferi a ma lò agbara lori wọn, ati awọn ẹni-nla ninu wọn a ma fi ọlá tẹri wọn ba.

Mat 20

Mat 20:17-27