Yorùbá Bibeli

Mak 1:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hà si ṣe gbogbo wọn, tobẹ̃ ti nwọn fi mbi ara wọn lẽre, wipe, Kili eyi? ẹkọ́ titun li eyi? nitoriti o fi agbara paṣẹ fun awọn ẹmi aimọ́, nwọn si gbọ́ tirẹ̀.

Mak 1

Mak 1:22-32