Yorùbá Bibeli

Luk 9:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnu si yà gbogbo wọn si iṣẹ ọlánla Ọlọrun. Ṣugbọn nigbati hà si nṣe gbogbo wọn si ohun gbogbo ti Jesu ṣe, o wi fun awon ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe,

Luk 9

Luk 9:35-49