Yorùbá Bibeli

Luk 9:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti mbọ̀, ẹmi èṣu na gbé e ṣanlẹ, o si nà a tantan. Jesu si ba ẹmi aimọ́ na wi, o si mu ọmọ na larada, o si fà a le baba rẹ̀ lọwọ.

Luk 9

Luk 9:32-44