Yorùbá Bibeli

Luk 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ ni Jakọbu ati Johanu awọn ọmọ Sebede, ti nṣe olupẹja pọ pẹlu Simoni. Jesu si wi fun Simoni pe, Má bẹ̀ru; lati isisiyi lọ iwọ o ma mú enia.

Luk 5

Luk 5:3-19