Yorùbá Bibeli

Luk 19:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si ngbọ́ nkan wọnyi, o fi ọ̀rọ kún u, o si pa owe kan, nitoriti o sunmọ Jerusalemu, ati nitoriti nwọn nrò pe, ijọba Ọlọrun yio farahàn nisisiyi.

Luk 19

Luk 19:9-13