Yorùbá Bibeli

Luk 18:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si gbé awọn ọmọ-ọwọ tọ̀ ọ wá pẹlu, ki o le fi ọwọ́ le wọn; ṣugbọn nigbati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ ri i, nwọn mba wọn wi.

Luk 18

Luk 18:8-25