Yorùbá Bibeli

Luk 14:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dahùn o wi fun wọn pe, Tani ninu nyin ti kẹtẹkẹtẹ tabi malu rẹ̀ yio bọ sinu ihò, ti kì yio si fà a soke lojukanna li ọjọ isimi?

Luk 14

Luk 14:1-14