Yorùbá Bibeli

Luk 14:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O si ṣe, nigbati o wọ̀ ile ọkan ninu awọn olori Farisi lọ li ọjọ isimi lati jẹun, nwọn si nṣọ ọ.

2. Si kiyesi i, ọkunrin kan ti o li asunkun mbẹ niwaju rẹ̀.