Yorùbá Bibeli

Luk 14:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o wọ̀ ile ọkan ninu awọn olori Farisi lọ li ọjọ isimi lati jẹun, nwọn si nṣọ ọ.

Luk 14

Luk 14:1-2