Yorùbá Bibeli

Luk 13:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ, ki ẹnyin si sọ fun kọ̀lọkọlọ nì pe, Kiyesi i, emi nlé awọn ẹmi èṣu jade, emi nṣe dida ara loni ati lọla, ati ni ijọ kẹta emi o ṣe aṣepe.

Luk 13

Luk 13:29-35