Yorùbá Bibeli

Luk 13:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni wakati kanna diẹ ninu awọn Farisi tọ̀ ọ wá, nwọn si wi fun u pe, Jade, ki iwọ ki o si lọ kuro nihinyi: nitori Herodu nfẹ pa ọ.

Luk 13

Luk 13:23-35