Yorùbá Bibeli

Luk 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli na si dahùn o wi fun u pe, Emi ni Gabrieli, ti ima duro niwaju Ọlọrun; emi li a rán wá lati sọ fun ọ, ati lati mu ìhin ayọ̀ wọnyi fun ọ wá.

Luk 1

Luk 1:10-21