Yorùbá Bibeli

Luk 1:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sakariah si wi fun angẹli na pe, Àmi wo li emi o fi mọ̀ eyi? Emi sá di àgba, ati Elisabeti aya mi si di arugbo.

Luk 1

Luk 1:13-27