Yorùbá Bibeli

Lef 8:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mú akọmalu wá fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ: ati Aaroni ati awọn ọmọ rẹ̀ fọwọ́ wọn lé ori akọmalu na fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ.

Lef 8

Lef 8:12-24