Yorùbá Bibeli

Lef 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si mú awọn ọmọ Aaroni wá, o si fi ẹ̀wu wọ̀ wọn, o si fi amure di wọn, o si fi fila dé wọn li ori; bi OLUWA ti fi aṣẹ fun Mose.

Lef 8

Lef 8:11-22