Yorùbá Bibeli

Lef 7:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọkàn na ti o ba jẹ ninu ẹran ẹbọ alafia, ti iṣe ti OLUWA, ti on ti ohun aimọ́ rẹ̀ lara rẹ̀, ani ọkàn na li a o ke kuro ninu awọn enia rẹ̀.

Lef 7

Lef 7:18-23