Yorùbá Bibeli

Lef 7:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹran ti o ba si kàn ohun aimọ́ kan, a kò gbọdọ jẹ ẹ; sisun ni ki a fi iná sun u. Ṣugbọn ẹran na ni, gbogbo ẹniti o mọ́ ni ki o jẹ ninu rẹ̀.

Lef 7

Lef 7:17-29