Yorùbá Bibeli

Joh 8:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn dahùn nwọn si wi fun u pe, Abrahamu ni baba wa. Jesu wi fun wọn pe, Ibaṣepe ọmọ Abrahamu li ẹnyin iṣe, ẹnyin iba ṣe iṣẹ Abrahamu.

Joh 8

Joh 8:33-41