Yorùbá Bibeli

Joh 8:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohun ti emi ti ri lọdọ Baba ni mo nsọ: ẹnyin pẹlu si nṣe eyi ti ẹnyin ti gbọ lati ọdọ baba nyin.

Joh 8

Joh 8:36-45