Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati bàta gbigbo ati lilẹ̀ li ẹsẹ̀ wọn, ati ẹ̀wu gbigbo li ara wọn; ati gbogbo àkara èse wọn o gbẹ o si hùkasi.

Joṣ 9

Joṣ 9:1-9