Yorùbá Bibeli

Joṣ 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn ṣe ẹ̀tan, nwọn si lọ nwọn si ṣe bi ẹnipe onṣẹ ni nwọn, nwọn si mú ogbologbo àpo kà ori kẹtẹkẹtẹ wọn, ati ìgo-awọ ọti-waini ti lailai, ti o ya, ti a si dì;

Joṣ 9

Joṣ 9:1-6